Tito TV

Tito TV TÍTÓBI NI OLUWA OLORUN KOSEUNTI
(8)

Oru ayò là má su ibi kò ní ṣẹlẹ̀ sí gbogbo wá Àmín loruko Jesu Kristi
19/06/2026

Gbogbo ìwọ to rí Amin se orí rẹ tomotomo kò ní gbàbode Amin loruko Jesu Kristi

Gbogbo alátakò ohun rere ní iwájú èmi àti ìwọ to rí àwòrán yí wo iná Ọlọ́run jo wọn wọlé Amin loruko Jesu Kristi 🙏🏻

Gbogbo ọwọ ibi ti enikeni gbe nítorí rẹ tomotomo ibi rẹ padà si lórí lase Èdùmàrè Amin loruko Jesu Kristi

Ìwọ abiyamo tó rí Amin se obìnrin àjòjì ko ni gbà ipò rẹ nínú ayé àwọn ọmọ rẹ láṣẹ Èdùmàrè Amin 🙏🏻🙏🙏🏻

Gbogbo ìwọ to rí Amin se wa rí Ògo ayé rẹ lọ Amin loruko Jesu Kristi 🙏🏻

Gbogbo ọkàn to tẹ Amin Ọlọ́run jẹ kí wọ́n rí Àánú gba kí Osù yí tó parí Amin

Ọlọ́run fi agbára rẹ fà mí dìde àti gbogbo ojú to rí àwòrán wo to rí Amin se 🙏🏻
18/06/2026

Ọjọ́ ayọ rẹ ko ní dibaje a bá ọ kalẹ láṣẹ Elédùmarè Àmín

Amin loruko Jesu èmi àti ìwọ tomotomo a ní jẹ ìkorò keyin ayé wà Aminnnnnnnn🙏🙏🏻🙏

Address

Lagos Harbour
11011

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Tito TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category