13/11/2025
OJO SUNDAY TI A DOJU KO YII NI O, KI OLOHUN JEKIA JU OJO NAA LO LAIYE (AMIN)
A nfi asiko yi ran gbogbo eyin ololufe anobi Muhammad s.a.w lara wa leeti,wipe ojo Sunday ti o nbo yii ni Maolid Nabiyy program tia pe yin si o,( November 16th 2025 )
Siwaju kio to wa dii ojo Sunday ti a ma se Maolid, enikeni toba nifesi ijoko adua ti yio waye ni ojo Friday November 14th ,anfani wa fun gbogbo wa lati darapo mon wa ninu ijoko JILSATUL MAGFIROH naa, ijoko adua naa yio bere lago mewa owuro, ti yio si pari ti akoko jumuat ba nto bo, beeni ao se ijoko HAILALATUL KUBROH nirole jumuat gege bi a se ma nse ninu ijo Maolanah shaekh ahamad tijani R.t.a,
Bee naa ni ijoko adua AS-SIYAAROH nbe lojo Saturday November 15th 2025, ijoko adua naa yio bere ni dede agogo mewa owuro, tiiti ago meji osan yio fi lu.
Toba wa dii ojo Sunday November 16th 2025, ni ijoko MAOLID NABIYY yio waaiye, a nreti gbogbo eyin ololufe anobi Muhammad s.a.w lara wa lati wa fii ijoko yin se aponle anobi Muhammad s.a.w, ki olohun se alekun gbigbadua gbogbo wa Amin
Eleyi ni itosona aaye ati adugbo tii awon ijoko naa yio tii waaiye, lati ibiyowu tia bati nbo, Budo nuhu ni international airport ilorin, ni ehin police station budo nuhu gangan ni awon eeto naa yio ti waiye.
Phone numbers tia le pe si fun itosona leleyi
09023068326, 08143437822