ASELA FILM Productions

ASELA FILM Productions I am here to give you comic scene, reasonable videos, fantastic songs, fabulous and non fiction write up

06/10/2024

HIGH CHIEF AWOLOWO AGBOJULEFA AWOGBILE, THE OLUAWO OF IKA ORANGUN'S EJIODI FESTIVAL AT IKA ORANGUN ON OCTOBER 6,2024 JINGLE BY OLUGBODI SAMSON ASELA (09062858740).

03/10/2024

O MA SE O
Bi eniyan to sun mo eniyan bajale
O se la a wi
Bi eniyan ta gboju okun le
O be Jo Eni agba
Irewesi a si ba eniyan

Aise dede ara aye ni i Muni
Ranti ara orun
O ma se o

Orile Ede yi
To ti fi igba kan ri dabi Amerika
Nlo kan gogo bi ibo
Ara ile o wa le ranse pe ara oko
Be e ni ara oko o ranse pe ara ile

A se bi Ile o ba dun
Bi igbe ni ilu ri
O wa di woro si woro
A ti jeun wa le koko bi oju EJA
Ati ri okele ti bo inu obe
Wa di oran

Ibo lagbami OSELU n gbe wa re
Se bi yo se maa ri lo re e
Ibo wa lafe ba yara ja bayi
Nigba ti aadota naira o to ra
OUNJE fun omo ikoko
Ka wa mo so tomo irinse

Eyin olori wa
E bape ara yin si AJO toni ironu
Ti a ba fowo leran
Ti e wa so ara yin di
Ari i gbodowi ikun imu baale

Mo fe ki e lo mo wi pe
A fi fila pa eerin
Ojo kan loni iyi mo

Oniwa nwi
Eleyin o gbo
Eleyin nso
Eleyin o gba
A gbe ilu sile
A tun fenu wi
Apoti alakara tanfe a ni

Bi OLUGBON o ba se e re
Awa okuku ni wi pe o se e re
Bi ARESA o ba se e re
Awa o kuku ni so wi pe o se e re

OGAGUN OLUSEGUN OBASANJO
Baba IYABO e ku afomo niyan se
Oloogbe MUSA YARADUA ki
OBA OLUWA o te o si afefe rere
Dokita GOODLUCK JONATHAN
Ki aye o tubo ma a ye o

Bi eniyan o se
Awa o ni so wi pe
O se e
Bi eniyan o ba se eniyan
Awa o ni so wi pe
O se e yan

Won ti ti gbogbo mekunnu sinu ibu
A fi ki OBA OLUWA ko wa yo
Ki OLUWA gba ORILE EDE yi fun
Ara re
Tori wi pe ara n ni wa

Owo epo bentiro won
A tun ri owo ra ounje je
Se aja toti yo wa le ba aja ti o yo sere

A kawe tan ko si ise
Sebi nitori k**a ba a jiya
Ni a se ya monjiya lofa

Oro kan ti a ti ngbo tipe tipe
Ni wi pe ODO NI OJO OLA ORILE EDE YI
Se odo ti kole da enu ara re bo
Se ohun ni yo di AARE ORILE EDE

ELEDUMARE jowo gba wa
Ara n ni wa o
OLUGBEJA wa gbe wa nija
ORILE EDE yi nfe ifowokan re
Dide ki o gbe wa nija

LATI OWO OLUGBODI SAMSON (ASELA)

29/09/2024

Make friends with reasonable people
Who make you happy
Do not make friends with people
Who make jest of you
Over your challenges

The way you picture yourself
In your mind
Can affect your happiness

Picture yourself as a valuable
Avoid low esteem
And inferiority complex

FROM THE TABLE OF COMRADE OLUGBODI SAMSON (ASELA)

18/09/2024

Hear me

18/09/2024

Our leaders

17/09/2024

AREA FATHER

16/09/2024
15/09/2024

Situation

10/09/2024

Not every questions required answer

Address

Ejemu's Compound, Ola-
Ejigbo

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ASELA FILM Productions posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category